Long time no see: Ó tó ọjọ́ mẹ́ta
|
I missed you: Àárò [yín / rẹ] sọ mí
|
What's new?: Kí ló nṣẹlẹ̀?
|
Nothing new: Kò sí nnkan kan
|
Make yourself at home!: [Ẹ] fi ọkàn [yín] balẹ̀!
|
Have a good trip: Ọ̀nà ire
|
Do you speak English?: Njẹ [ẹ / o] nsọ èdè Gẹ̀ẹ́sì?
|
Just a little: Díẹ̀ ṣá
|
What's your name?: Kínni orúkọ [rẹ / yín]?
|
My name is (John Doe): Orúkọ mi ni (John Doe)
|
Mr.../ Mrs. .../ Miss...: Ọ̀gbẹ́ni… / Aya… / Omidan
|
Nice to meet you!: Ó dára láti rí [yín / ọ]!
|
You're very kind!: [Ẹ / O] ní inú rere púpọ̀!
|
Where are you from?: Níbo ni [ẹ / o] ti wá?
|
I'm from the U.S: Ilẹ̀ Amẹrika ni mo ti wá
|
I'm American: Ọmọ ilẹ̀ Amẹrika ni mí
|
Where do you live?: Ibo ni [ẹ / o] ngbé?
|
I live in the U.S: Ilẹ Amẹrika ni mo ngbé
|
Do you like it here?: Njẹ́ [ẹ / o] fẹ́ bí ó ti rí níhín?
|
Who?: Tani?
|
Where?: Níbo?
|
How?: Báwo?
|
When?: Nígbà wo?
|
Why?: Kí ló fà á?
|
What?: Kínní?
|
By train: Nípa ọkọ̀ ojú irin
|
By car: Nípa ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́
|
By bus: Nípa ọkọ bọ́ọ̀sì
|
By taxi: Nípa ọkọ̀ ajé ìgboro
|
By airplane: Nípa ọkọ̀ òfúrufú
|
Malta is a wonderful country: Malta jẹ orílẹ̀-èdè ìyanu
|
What do you do for a living?: Iṣẹ́ óòjọ́ wo ni [ẹ / o] nṣe?
|
I'm a (teacher/ artist/ engineer): (Olùkọ́́ / Oníṣẹ́-Ọnà / Onímọ)̀-Ẹ̀rọ ni mí
|
I like Maltese: Mo fẹ́ràn èdè Malta
|
I'm trying to learn Maltese: Mo ngbìyànjú láti kọ́ èdè Malta
|
Oh! That's good!: Ìyẹn dára o!
|
Can I practice with you: Ṣé mo lè bá [ọ / yín] kọ́ ọ
|
How old are you?: Ọmọ ọdún mélòó ni [ọ́ / yín]?
|
I'm (twenty, thirty...) Years old: Ọmọ (oguń, ọgbọ̀n….) ọdún ni mi
|
Are you married?: Ṣé o / ẹ ti ṣe ìgbéyàwó?
|
Do you have children?: Ṣé [ẹ / o] ní àwọn ọmọ
|
I have to go: Mo ní láti lọ
|
I will be right back!: Mà á padà wá!
|
This: Èyí
|
That: Ìyẹn
|
Here: Ìhín / Ibí
|
There: Ọ̀hún
|
It was nice meeting you: Ó dára láti bá ọ / yín pàdé
|
Take this! (when giving something): [Ẹ] gbà èyí
|
Do you like it?: Ṣé [ẹ / o] fẹ́ ẹ?
|
I really like it!: Mo fẹ́ ẹ nítòótọ́!
|
I'm just kidding: Mo kàn nṣeré ni!
|
I'm hungry: Ebi npa mí
|
I'm thirsty: Òngbẹ ngbẹ mí
|
In The Morning: Ní Òwúrọ̀
|
In the evening: Ní àṣálẹ́
|
At Night: Ní Òru
|
Really!: Nítòótọ́!
|
Look!: Wò ó!
|
Hurry up!: Yára! / Múra!
|
What?: Kínni?
|
Where?: Níbo?
|
What time is it?: Àkókò wo ni? / Aago mélòó? / Kínni aago sọ?
|
It's 10 o'clock: Aago mẹ́wàá ni ó lù
|
Give me this!: [Ẹ] Fún mi ní èyí!
|
I love you: Mo nífẹ̀ẹ́ [rẹ / yín]
|
Are you free tomorrow evening?: Ṣé wàá ráàyè ní ìrọ̀lẹ́ ọ̀la?
|
I would like to invite you for dinner: Mo nfẹ́ láti pè [ọ́ / yín] síbi àsè
|
Are you married?: Ṣé [ẹ / o] ti ṣe ìgbeyàwó?
|
I'm single: Mi ò tíì ṣe ìgbeyàwó
|
Would you marry me?: Ṣé [ẹ / o] ó fẹ́ mi?
|
Can I have your phone number?: Ṣé [ẹ / o] lè fún mi ní nọ́mbà ẹ̀rọ ìbániṣọ̀rọ̀ [yín / rẹ]̀?
|
Can I have your email?: Ṣé [ẹ / o] lè fún mi ní ímeèlì yín / rẹ
|
You look beautiful! (to a woman): [Ẹ / O] rẹwà!
|
You have a beautiful name: Orúkọ [rẹ / yín] rẹwà
|
This is my wife: [Ìyàwó / Aya] mi nìyí
|
This is my husband: Ọkọ mi nìyí
|
I enjoyed myself very much: Mo gbádùn ara mi gidigidi
|
I agree with you: Mo fi ara mọ́ ohun tí [ẹ / o] sọ
|
Are you sure?: Ṣé ó dá ọ / yín lójú?
|
Be careful!: [Ẹ] ṣọ́ra! / [Ẹ] kíyèsára!
|
Cheers!: [Ẹ / O] Gbayì!
|
Would you like to go for a walk?: Àbí [ẹ / ọ] ó rìn jáde lọ?
|
Holiday Wishes: [Ẹ / O] kú ìsinmi lẹnu iṣẹ́
|
Good luck!: [Ẹ / O] ó ṣoríire!
|
Happy birthday!: [Ẹ / O] kú ọjọ́ ìbí!
|
Happy new year!: [Ẹ / O] kú ọdún tuntun!
|
Merry Christmas!: [Ẹ / O] kú ọdún Kérésìmesì!
|
Congratulations!: [Ẹ / O] kú oríire!
|
Enjoy! (before eating): [Ẹ] máa gbádùn!
|
Bless you (when sneezing): Ìbùkún ni fún yín!
|
Best wishes!: Ire o!
|
Transportation: Ìgbòkègbodò ọkọ̀
|
It's freezing: Ó ndì
|
It's cold: Ó tutù
|
It's hot: Ó gbóná
|
So so: Bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ |
|