Vocabulary

Phrases

Grammar

Yoruba Mistakes

This is a list of mistakes in Yoruba. Helpful when trying to learn a new word. Also useful when there is a misunderstanding or confusion.

My French is bad: Èdè Faranse mi kò dára
I need to practice my French: Mo ní láti máa ṣe àgbéyèwò èdè Faranse mi
Don't worry!: Má ṣe ìyọnu!
Excuse me? : Ẹ jọ̀wọ́?
Sorry: Ẹ má bínú
No problem!: Kò séwu
Can you repeat?: Njẹ́ ẹ̀ lè tún u sọ?
Can you speak slowly?: Njẹ́ ẹ lè rọra sọ̀rọ̀?
Write it down please!: Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ ọ́ sílẹ̀!
I don't understand!: Kò yé mi!
Did you understand what I said?: Njẹ́ ohun tí mo sọ yé ọ / yín?
What is this?: Kí ló fà èyí?
I don't know!: Mi ò mọ̀!
What's that called in French?: Kínni a npè iyẹn ní èdè Faranse?
What does that word mean in English?: Kínni ìtùmọ̀ ọ̀rọ̀ yẹn ní èdè Gẹ̀ẹ́sì?
How do you say "OK" in French?: Báwo ni ẹ ti nsọ pé "Ó́ dára" ní èdè Faranse?
Is that right?: Ṣé ìyẹn tọ̀nà?
Is that wrong?: Ṣé ìyẹn kò tọ̀nà?
What should I say?: Kí ló yẹ kí nsọ?
What?: Kínni?

These are some words from the above sentences that you might also need to use by themselves.

Mistake: Àṣìṣe
To speak: Láti sọ̀rọ̀
Slowly: Díẹ̀díẹ̀
Quickly: Kíákíá

Hopefully the expressions for mistakes in Yoruba can help you clear some misunderstanding and allow you to ask questions. Check out the next topic below or choose your own subject from the menu above.

Yoruba AnimalsPrevious lesson:

Yoruba Animals

Next lesson:

Yoruba Shopping

Yoruba Shopping