Hi!: Báwo!
|
Good morning!: [Ẹ / O] káárọ̀!
|
Good afternoon!: [Ẹ / O] káàsán!
|
Good evening!: [Ẹ / O] kú ìrọ̀lẹ́!, [Ẹ / O] kú alẹ́!
|
Welcome!: [Ẹ / O] kú àbọ̀!
|
How are you? (friendly): Báwo ni?
|
How are you? (polite): Ṣé dáadáa ni?
|
What's up? (colloquial) : Kí ló nṣẹlẹ̀?
|
I'm fine, thank you!: Mo wà dáadáa, [ẹ / o] ṣeun!
|
And you? (friendly): [Ìwọ / Ẹ̀yin] náa nkọ́?
|
And you? (polite): [Ìwọ / Ẹ̀yin] náa nkọ́?
|
Good: Dára
|
Bad: Kò dára
|
Happy: Inú rẹ̀ dùn
|
Sad: Inú rẹ́ bàjẹ́
|
Thank you!: [Ẹ / O] ṣe[un]!
|
Thank you very much!: [Ẹ / O] ṣe púpọ̀!
|
You're welcome!: [Ẹ / O] káàbọ̀!
|
Have a nice day!: Ó dàbọ̀!
|
Good night!: Ó dàárọ̀!
|
See you later!: Ó dìgbà kan ná!
|
Have a good trip!: Ọkọ̀ á rèfó!
|
It was nice talking to you!: Ìjíròrò mi pẹ̀lú rẹ / yín ládùn |
|